IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 19 September 2018

OLUKAYODE SALAKO DI AKOWE GBOGBOGBOO BUHARI/OSINBAJO MANDATE GROUP

Ogbeni Olukayode Salako to je alakooso fun ajo to n ri si ipadabo  sa a keji fun Aare Muhammed Buhari ati Osinbajo,iyen, 'Buhari/ Osinbajo Mandate Group' nile Yoruba, ti di akowe gbogbogboo egbe naa bayii. Alaga igbimo baba isale ajo yii, Dokita Sani Abdallah lo fowo si  iyansipo Salako yii. 

Bakan naa la gbo pe won ti gba ipo alakooso patapata ajo naa kuro lowo Omooba Ebunola Martins to wa nipo yii tele, won ti yan adari banki agba ile wa tele, Mohammed Ali Baba gege bii alakooso gbogbogboo tuntun bayii



No comments:

Post a Comment

Adbox