Fawon ti ko ba ti i gbo, ojo kefa, osu kewaa, odun yii ni gbajumo olorin Islam nni, Alaaji Monsurat Ajelero Adegbemiro ti gbogbo aye mo si Akobi-Esan yoo sayeye onibeta. Ayeye ohun nifilole awo re tuntun to pe ni 'Ta n tolohun', ifilole egbe awon ololufe e ati ifilole ajo alaanu to fi fee maa ran awon eeyan lowo.
Inu gbongan ijoba ibile Ado- Odo Ota, nipinle Ogun layeye yii yoo ti waye. Awon olorin Islam yoo forin dara nibe lojo yii.
Bakan naa ni Ojutole gbo pe ankara ti won mu fun ayeye yii ti wa fun tita bayii. Enikeni to ba fee ra ankara, e pe Akobi Esan sori nomba yii:08035993303
No comments:
Post a Comment