IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday, 24 September 2018

OGA ILEESE YEFADOT, OLOYE YETUNDE BABAJIDE FEE SAYEYE OJOOBI LARA OTO

Ojo kin in ni osu kewaa odun yii ni gbajugbaja onisowo, oloselu ati ajafetoo omoeniyan, Oloye Yetunde Babajide, oga ileese Yefadot Group of companies  to tun je asaaju awon obinrin nile Yoruba fun ajo to n ri si bi Aare Muhammed Buhari yoo wole leekan si i iyen 'National Committee of Buhari Support groups' yoo sa
yeye ojoobi e.

Ojutole gbo pe gbogbo eto  bi ojo naa yoo se larinrin,ti yoo dun daadaa lo ti wa nile bayii. Gbongan 'Gabovis Hall' to wa ni Ojodu, nipinle Eko la gbo pe ayeye nla ohun yoo ti waye, nibi tawon eeyan yoo ti janfaani nla lojo yii.

Bi ayeye ojoobi naa  ba se lo ni Ojutole yoo mu wa fun yin. 

No comments:

Post a Comment

Adbox