IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 23 September 2018

O GA O, LEYIN OSU META TOKO E KU, EFE, IYAWO RAS KIMONO JADE LAYE

Iroyin aburu to te Ojutole lowo bayii ni pe, Efemena Okedi, iyawo agba-oje olori raga, Ras Kimono to ku losu meta seyin naa tun ti jade laye.
Gege bi a se gbo, aaro ojo Aiku, Sannde lobinrin naa deede ku sile e to wa niMagodo, nipinle Eko, ko si seni to ti i mo iru iku to pa obinrin naa.
Kinni kan ti gbogbo awon eeyan to gbo nipa iku ojiji to pa obinrin yii
n so ni pe eleyii ma tun ga o 

No comments:

Post a Comment

Adbox