Saaju keto idibo ipinle Osun too waye lojo Abameta, Satide to koja yii ni oludasile ijo 'INRI Evangelical Spiritual church, Primate Babatunde Elijah Ayodele ti asotele nipa ibo yii ninu iwe e to pe ni 'Warning to the Nation'.
Loju ewe karundinlogofa (115) iwe yii ni Primate Ayodele ti so pe egbe APC yoo ni isoro nla ti yoo je ki won padanu ibo naa ti won ko ba mura.
'Gomina tuntun ni yoo wole l'Osun, ti yoo gbe ipinle naa de ile ileri. Makaruru ati wahala yoo sele lasiko idibo yii. Omisore ko le e wole ibo gomina l'Osun, ti APC ba fee wole, won gbodo lo ogbon oselu lati wa nipo yii'
.
No comments:
Post a Comment