IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 26 September 2018

O PARI: OMISORE NI APC LOUN YOO SISE FUN INU ATUNDI IBO OSUN TI YOO WAYE LOLAo

Boya ni igbakeji gomina ipinle Osun tele, Senato Iyiola Omisore, ko ni i ba nnkan je fegbe oselu PDP ninu atundi ibo ti yoo waye nipinle Osun lola, idi ni pe okunrin oloselu toun naa dije ninu egbe oselu SDP ti so pe egbe APC loun atawon ololufe oun yoo sise fun lola. 
Ofiisi e lo ti soro ohun laaro oni-in. Ohun to so ree o, 'Egbe oselu APC ni la n ba lo bayii, awon la o sise fun loa'.
Saaju ki Omisore too kede pe oun yoo sise fun APC lola ni alaga gbogbogboo egbe APC, Ogbeni Adams  Oshiomhole,  Abdullahi Ganduje, gomina ipinle Kano state, Senato Abiola Ajimobi, gomina ipinle  Oyo; Senato Ibikunle Amosun, gomina ipinle Ogun,  Muhammad Baduru, gomina ipinle Jigawa. Alaaji Lai Mohammed, minisita fun eto iroyin ati Alaaji  Yusuf Lasun, igbakeji olori ile igbimo asoju-sofin.
Pelu ohun ti Omisore se yii, yoo nira fun egbe oselu PDP lati jawe olubori lola
OMISORE ATAWON GOMINA APC ATI ALAGA WON
 

No comments:

Post a Comment

Adbox