
Fawon ti ko ba gbo, abi awon ti won ti gbagbe, odun to koja ni Damilola segbeyawo alarede pelu iya omo tuntun yii, iyen leyin ti aarin oun ati iyawo e tele, Mujeedat, toun naa je gbajumo olorin Islam daru.
Omo merin, iyen Taye,Kehinde,Idowu ati Alaba ni Mujedat bi fun oko e,ki wahala to o sele laarin won,won ko si ri i yanju di bi a se n so yii. Olorun yoo wo omo tuntun yii, yoo soriire
, yoo si lalubarika nla
No comments:
Post a Comment