IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 7 September 2018

O GA O: IYAALE-ILE BI ELEDE NILE IBO

Omobinrin kan lawon eeyan n soro e kiri nile Ibo bayii, ko si ohun to fa eyi ju omo tuntun ti omobinrin naa bi to dabii elede lo.

Ileewosan aladani kan la gbo pe omobinrin yii bimo si, sugbon bomo yii se jabo lara e lo di ohun to ya dokita atawon noosi to gbebi fun un lenu, omo to fara jo elede lomobinrin yii bi.

Ohun to sele yii la gbo pe o fa ogbe okan fobinrin yii atawon ebi e, won ko si ti i mo ohun ti won yoo se si omo y
ii. 

No comments:

Post a Comment

Adbox