IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 1 September 2018

O MASE O,ALAAJA SAUDI, OLORIN FUJI TI KU O

Ajalu ti ko seni to gbadura re lo sele lagbo awon onifuji wa, okan ninu won, Alaaja Saudi lo ku lojiji. Ohun to je kiku obinrin naa ka awon eeyan lara, to si bawon lojiji  ni pe, ko saisan nla, lojiji ni kinni ohun ki i mole, to si gba emi e.

Ojutole gbo pe obinrin yii si korin niluu Oyo lojo odun Ileya to koja yii, bee lo soro lori ero ayelujara lojo ketadinlogbon osu yii.

Ki Olorun fori ji i, ko duro ti awon omo to fi sile saye lo.


 

No comments:

Post a Comment

Adbox