IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 1 September 2018

OJO NLA LOJO TI GBAJUMO OLORIN EMI, OBA ARA SAYEYE OJOOBI BONKELE FOMO E, IREAYOMIDE

Bo tile je pe okunrin naa ko se kinni ohun lalariwo, ko fe kawon eeyan pupo gbo nipa e, sugbon awon ebi e ko gbeyin nibi ayeye ojoobi  naa.

Ayeye ojoobi ti gbajumo olorin emi nni, Efanjeliisi Dokita Oluwarotimi Michael Onimole ti gbogbo aye mo si Oba Ara se fun omo e, Ireayomide Hezekiel Onimole to sese de lati London la n so, o jare.

Ojo Abemeta, Satide, to koja lohun-un layeye ohun waye, eni to ba si wa nibe yoo mo pe inu Oba Ara atiyawo e, Olori Afolashade Onimole dun koja aala.

Bi jije  se kunle rekereke, bee ni mimu naa wa, tawon omode ti won wa sibe tun di ebun nla lo sile won.

Ojutole sadura fun Ireayomide pe yoo se opolopo odun laye, yoo dagba, yoo dogbo,
































yoo soriire lagbara Olorun. 

No comments:

Post a Comment

Adbox