IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 26 September 2018

MOSHOOD ADEOTI TO DIJE LABE EGBE OSELU ADP NAA TI PADA SINU APC BAYII, O LOUN WA LEYIN OYETOLA

Ondije labe egbe oselu ADP ninu ibo gomina ipinle Osun to koja yii, Alaaji Moshood Adeoti,
naa ti pada sinu egbe oselu APC to ti kuro. Igbese yii waye leyin tawon asaaju egbe oselu APC sepade pelu e laaro yii.

Pelu ohun to sele yii, yoo nira fun PDP lati gbajoba lowo egbe oselu APC l'Osun ninu atundi ibo ti yoo waye lola.

No comments:

Post a Comment

Adbox