Faaji nla yii yoo waye ni 'Cafe De Vivre' 14165 Bissonet Street, Suite P, Houston Texas. Lati aago mesan-an ale di aaro ojo keji lariya yii yoo fi waye.
Lasiko to n ba Ojutole soro, Mayor Alamu so pe gbogbo awon ololufe orin fuji ni won yoo jegbadun orin aladun latowo oun lojo naa. O ni awon orin gidi ati alujo ti won ko gbo ri ni won yoo gbadun daadaa lojo naa.
No comments:
Post a Comment