Oludije ipo gomina labe egbe oselu PDP, nipinle Osun, Senato Ademola Adeleke, ti so pe ko si ohun to n je atundi ibo ninu ibo gomina to waye nipinle Osun lanaa. Okunrin yii so pe ko si ohun ti a fee pe eyi ju ifote-gbajoba tawon oloyinbo n pe ni coup lo.O ni ko si ohun meji to ye ajo INEC ju pe ki won kede oun gege bii gomina ipinle naa, koun si ma a se ijoba oun lo.
Sugbon ohun tawon APC so ni pe Josefu Alaala kan bayii lokunrin naa,won ni ko tete dide loju orun,
nitori pe ala lo n la, o jare.

No comments:
Post a Comment