IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 19 September 2018

IROYIN YAJOYAJO: AWON ADIGUNJALE FOPO EMI SOFO NILEFOWOPAMO UNION NI IGEDE-EKITI

Nnkan ko rogbo niluu Igede-Ekiti, nipinle Ekiti,pelu bawon adigunjale kan se yabo won nilefowopamo 'Union' to wa niluu naa. Lojuese ni won ti pa awon aso aabo to wa nibe, awon osise ileewopamo yii atawon onibaara won naa faragba ninu e.
Leyin tawon adigunjale yii pa awon eeyan tan, ni won gbe roburobu owo lo. Ojutole gbo pe awon olopaa ti bere ise lati wa awon adigunjale  yii kan


 



No comments:

Post a Comment

Adbox