Ayeye ohun ni ifilole rekoodu e tuntun to pe ni 'Ta-n-tolohun', ifilole ajo alaanu ti ki i se tijoba to pe ni 'Akobiesan Foundation' ati ifilole egbe awon ololufe e ti won pe ni 'Akobiesan National Fans Club'.
Agba oniwaasi ti yoo se waasi lojo naa ni Sheik Dokita Muheeden Ajani Bello, nigba ti gbajugbaja olorin Islam nni, Alaaji Mistura Aderohunmu Asafa tawon eeyan mo si Temi-ni-success ni yoo korin nibi ayeye ohun.
Ankara egberun merin naira lawon eeyan yoo fi wole sibi ayeye yii. Ninu oro Akobiesan lo ti ro gbogbo awon ololufe e lati waa fi ojo naa ye e si.
No comments:
Post a Comment