Gege bi enikan to sunmo Gomina ti won tun n pe ni Iroko yii se so fun wa, to tun fi foto ipade to n lowo l'Abuja lowo sowo si wa, o ni egbe 'Labour Party' lokunrin naa ti fee jade dupo aare.
A gbo pe ohun ti gomina atijo yii so ni pe leyin ipade ati ifikunlukun toun se pelu awon eeyan oun, oun naa setan dupo aare bayii. Ti yoo ba fi di aaro ola, Mimiko yoo kede ipinnu re yii fawon omo orile-ede yii.
No comments:
Post a Comment