IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 7 September 2018

GBAJUMO OLORIN EMI, AYANFE JESU, FEE SETO 'UNLIMITED PRAISE 2018'

Okan ninu awon olorin emi ti won n se daadaa lorile-ede yii ni Efanjeliisi Stella Elegbeleye tawon eeyan mo si Ayanfe Jesu. Obinrin naa fee seto orin iyin ati ope to pe ni 'Unlimited Praise 2018'

Ojo kejidinlogbon, osu kewaa, odun yii leto naa yoo waye lojule kerinla, opopona Moshood Ekun, legbee, Mydinal Rental,Alausa,Lambe 2nd juction.

Lara awon olorin ti won yoo forin yin Olorun logo lojo naa ni:Efanjeliisi Dokita Oluwarotimi Onimole Oba Ara, Efanjeliisi Paul Omo Abule, Arewa Ayangbayi, Otunba Dele Oludele, Efanjeliisi Aduke Gold, Omo Edumare, Alpha P, Biyi Samuel ati Alapaloyin Crew.


Alaga ojo naa ni:Onarebu Dayo Saka Fafunmi,nigba ti baba ojo naa yoo je Pastor Adetayo. Mama ojo naa ni Arabinrin T. Abiola Eni ti yoo dari eto yii  Ojo Olusegun.

No comments:

Post a Comment

Adbox