Eni ti yoo gba awon eeyan lalejo ni Eniowo Adekunle Adedeji tawon eeyan tun mo si Kunle Omo Alaafin Orun. Eto naa yoo bere lati ojo Eti, Fraide, ojo kejidinlogbon, osu kesan-an, laago mefa-abo irole, Ojo Abameta, Satide, ojo kokandinlogbon, osu kesan-an, laago mesan-an aaro ati ojo Aiku, Sannde, ogbonjo, laago mesan-an aaro ati aago mefa-abo irole.
Oniwaasu ojo naa ni Refurendi Dokita Godwin Okon nigba ti Pasito Elizabeth Obilana je olugbalejo keji
No comments:
Post a Comment