IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday, 3 September 2018

ONI LOJOOBI OLOLUFE WA, E JE KA BA OBA ARA DUPE LOWO OLORUN

Gbogbo wa pata nileese Ojutole la ba eeyan wa pataki,ore wa, oluranlowo wa ati gbajugbaja olorin emi,  Dokita Efanjeliisi Oluwarotimi Onimole ti gbogbo aye mo si Oba Ara dupe lowo Olorun fun ayeye ojoobi won to waye loni-in
 Adura wa ni pe ki Omo Onimole sopo odun laye ninu owo nla, ola nl ati alaafia jaburata. Igba odun, iseju aaya ni fun Oba Ara ti wa.

No comments:

Post a Comment

Adbox