IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday, 3 September 2018

MAYOR AKEEM ALAMU, ONIFUJI, DARABA NLA L'AMERIKA

Lowo yii ti won ba n daruko awon onifuji taye n fe ti won lorile-ede Amerika, ti oruko won rinle daadaa lorile-ede naa,  o daju saka pe won yoo daruko gbajumo osere fuji nni, Mayor Akeem Alamu si i.

Lojumo to mo loni-in, lara awon onifuji tawon ara Amerika ki i forin e sere lokunrin yii, osere nla naa ti daraba tapa omode koka, o ti digi aloye saari awon alawo funfun.

No comments:

Post a Comment

Adbox