IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Thursday, 20 September 2018

GBAJUGBAJA AAFAA, OLUOMO KUTONU FEE GBA AMI-EYE L'EKOO

Gbajugbaja aafaa, to tun je dokita to n sise itusile, Alaaji Dokita Babatunde Saheed tawon eeyan mo si Oluomo Kutonu yoo gba ami-eye nla lojo kerinla, osu kewaa, odun yii.

Gbajumo olorin Islam nni, Alaaja  Bilikis Olasode Fisayomi to ni egbe orin 'Islamic Royal Singers' lo fee fun Oluomo lawoodu yii fun ipa ribiribi to ti ko fun ilosiwaju ati idagbasoke esin Islam.

Gbongan 'Glorious Multipurpose Hall' to wa l'Abule-Egba layeye naa yo ti waye.

No comments:

Post a Comment

Adbox