Titi dasiko yii lawon akekoo ileewe giga Ambrose Alli University, to wa niluu Ekpoma, nipinle Edo si n baraje pelu bawon omo egbe okunkun se yinbon pa awon omoleewe mewaa. Lasiko ayeye ikekoo-jade tawon akekoo yii se laduugbo kan ti won n pe ni Judges's Quarter ni Ekpoma ni wahala yii ti sele.
Ojutole gbo pe ija lo sele laarin okan ninu awon omo egbe okunkun yii pelu elomi-in, ti won si bawon pari e, sugbon omo egbe okunkun yii so pe oun ko ni i gba afi ti eni to ba oun ja yii ba ra aso mi-in foun.
Pelu ibinu la gbo pe o fi kuro nibi ayeye yii, sugbon laarin iseju mewaa lo pada wa pelu awon ore e,ti won sina ibo bo awon akekoo yooku. Eni to ba a ja lo koko yinbon pa, ko too pa awon mesan-an mi-in
.

No comments:
Post a Comment