IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 26 August 2018

GBAJUGBAJA OLORIN EMI, BALOGUN PETERS AKETANTAN SOJOOBI LONI-IN, A BA A DUPE LOWO OLORUN

Oni-in, ojo kerindinlogbon osu kejo, odun 2018 ni gbajumo olorin juju, Balogun Peters Aketantan sayeye ojoobi e. Gbogbo wa pata nileese www.ojutole.com, iroyinojutole-toko.blogspot.com ati ojutole online tv la ba eeyan wa daadaa yo.

A gbadura pe ki Omo Balogun sopo odun laye ninu ola, owo, alaafia ara ati opolopo arisiki. Igba odun, iseju aaya ni fun ore wa pataki

No comments:

Post a Comment

Adbox