IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 26 August 2018

ONI LOJOOBI OTUNBA JESU OLORIN EMI,AWA NAA BA A DUPE LOWO OLORUN

A ba eeyan wa daadaa, Otunba Jesu ti gbogbo aye mo si Mr.Spirit dupe lowo Olorun fun ayeye ojoobi e to waye loni-in. Adura wa ni pe ki Otunba se opo odun laye ninu ola, owo, omo alalubarika ati alaaafia ara.

Igba odun,iseju aaya ni

No comments:

Post a Comment

Adbox