IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 25 August 2018

AWENI ONIWAKA LO N SOJOOBI, GBOGBO WA LA KI ALAAJA AMUDALAT KU ORIIRE

Gbogbo wa pata nileese www.ojutole, iroyinojutole-toko.blogspot.com ati ojutole online tv la ki eeyan wa daadaa, Alaaja Amudalat Aweni ti gbogbo aye pata mo si Aweni Oniwaka, ku oriire ojoobi won to waye loni-in.

Adura wa ni pe ki Alaaja se opo odun laye ninu ola, owo, ola, alaafia ati ohun meremere. E ku oriire o

No comments:

Post a Comment

Adbox