IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 28 August 2018

E JA KA BA BISOLA TESTIMONY, OLORIN EMIN, SAJOYO OJOOBI E

Oni lojoobi gbajumo olorin emin nni, Bisola Testimony, a ba ogbontarigi akorin yii dupe lowo Olorun pe ojo oni-in soju e.




A gba a ladura pe ki Bisola Olofada sopo odun laye ninu ola, owo, ola ati alaafia ara to peye. Hapi Batide, Bisola tiwa

No comments:

Post a Comment

Adbox