IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 28 August 2018

ALBUSHRAH AKORIN GBESIN GA REE O, ONI LOJOOBI E

Gbogbo wa pata nileese www.ojutole, ojutole online tv ati iroyinojutole-toko la ki eeyan wa daadaa, Alaaji Sulaiman Sharafadeen ti gbobo aye mo si Albushrah ku oriire ayeye ojoobi won.

A sadura fomo olojoobi pe yoo se opolopo odun laye ninu ola, owo repete ati alaafia to peye. Igba odun, iseju aaya ni fun akorin gbesin ga, Albushrah olorin oba.
 

No comments:

Post a Comment

Adbox