IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 24 August 2018

OPE O: YINKA AYEFELE ATI AJIMOBI TI PARI IJA O

Iroyin ayo to te wa lowo bayii ni pe  gomina ipinle Oyo, Senato Abiola Ajimobi ati gbajugbaja olorin gospel-tugba, Efanjeliisi Yinka Ayefele ti pari ija to sele nitori ileese radio Ayefele tijoba Oyo wo laipe yii.  




Ipade yii ti Alaafin ilu Oyo, Oba Lamidi Adeyemi atawon Oba Alaaye mi-in nile Yoruba wa nibe ni won ti yanju aawo yii, lojuese ni Ajimobi gbe igbimo kan kale pe ko sewadii bi oro ileese radio naa se je.
Gomina sapejuwe Ayefele gege bii eeyan daadaa, bee lo fi i lokan bale pe awon yoo yanju oro naa, ti wahala to sele yii yoo fi yanju patapata. 




No comments:

Post a Comment

Adbox