IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 25 February 2018

OPE O :OLORI MEMUNAT,IYAWO ALAAFIN BIBEJI

Taofik Afolabi
Iroyin ayo to te wa lowo bayii ni pe okan ninu awon iyawo Alaafin, Oba Lamidi Olayiwola Atanda, iyen, Olori Memunat Adeyemi, bibeji. Alaafia la gbo pe iya atawon ejire wa.

A ba Iku Babayeye dupe lowo Olorun fun oore ayo ti Eledua se fun won yii.

No comments:

Post a Comment

Adbox