IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 21 February 2018

Gbajumo olorin emi nni, Efajeliisi Rotimi Onimole Oba Ara yoo korin nibi ayeye oku iya Yomi Fabiyi

Taofik Afolabi
Gbajugbaja akorin emi nni, Efajeliisi Dokita Oluwarotimi Onimole, ti gbogbo aye mo si Oba Ara,
yoo forin aladun da awon eeyan laraya nibi ayeye asekagba oku Madam Adijat Kubrat Folawe, iyen mama to bi ilu mo on ka osere ori itage ti gbogbo awon eeyan feran, Abayomi Lukmon Fabiyi.

Ojo keta, osu keta, odun yii layeye naa yo waye ninun gbongan 'Blueroof' to wa ninu ogba ileese telifisan 'LTV' opopona Lateef Jakande, Agidingbi, Ikeja. 


Ankara elegberun meta naira lawon eeyan yoo fi wole sibi ayeye naa, fun ankara ti yin, e pe nomba yii: 08089069479.
.
Awon omo igbimo eto isinkuu naa ni Sola Kosoko (Alaga) Kemi Afolabi (Akowe Ipolongo)
Taiwo Adebayo Sheboy (Akowe}

1 comment:

  1. Oba ara on the stage, o ma loud gan niyen o. Brilliant. Go broa

    ReplyDelete

Adbox