IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 2 February 2018

Babalola Alex ree,ori eeyan gbigbe ni won ka mo on lowo l'Ogun

Taofik Afolabi
Àwọn olopaa ìpínlẹ̀ Ogun tí mú ọkùnrin kan torúkọ rẹ ń jẹ Babalola Alex, orí èeyàn ni won ka  mọ ọn lọ́wọ́ lagbegbe Asese, nikoja Ibafo, nipinle Ogun. Okunrin yii tí jewọ wí pé ọ̀dọ̀ babaláwo tó fẹ́e bá òun ṣoogún owó lòun gbé orí gbigbe  náà lọ. Awon olopaa ti so pe tawon ba ti pari iwadii awon lawon yoo taari re lo sile-ejo fun ijiya ohun to se yii.

No comments:

Post a Comment

Adbox