IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday, 29 January 2018

Gbogbo eyin alafe,e ku imurasile fun rekoodu tuntun latowo Anjola Bravo

Iroyin to te wa lowo lati odo ilu mo on ka osere juju,to tun je oba orin juju lorile-ede Ireland, King Anjola Leo Bravo,
  ni pe osere naa ko ni i pe e wo ile agodo, ti yoo ti po orin gidi sile fun igbadun awon ololufe.
Gbogbo eyin alafe gbogbo, iroyin ayo kan ree o, e maa mura sile fun rekoodu tuntun latowo ololufe yin,Bravo Anjola. 

No comments:

Post a Comment

Adbox