IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 4 August 2021

Kabieesi Oba Barrister Johnson Adebola Okubena Sayeye ojoobi, A Ki Alayeluwa Ku Oriire

A n ki Kabiyesi Alaiyeluwa *Oba Barrister Johnson Adebola Okubena - Adara'le-d'oye 2, The Elerunwon of Erunwon-Ijebu* ku ti ajoyo ayeye ojo-ibi won loni yii *Thursday ojo karun-un osu kejo odun 2021* ni Aafin Elerunwon ti ilu Erunwon-Ijebu, ni ipinle Ogun. Igba odun, odun kan ni baba. Kaaaabiyesi ooooo.

Greetings from Dr. & Mrs. Mate (Ifankalleluyah).

No comments:

Post a Comment

Adbox