Okan gboogi binu awon omo orileede yii ti won n se daadaa nidii ise orin lorileede Amerika ni Omooba Rokan Adekola ti gbogbo aye mo si King Rokan.
Omooba ilu Iboropa Akoko naa sese ra moto olowo nla ti oruko n je Benz 4matic ni. Lasiko ti okunrin naa n ba ojutole soro, o loun dupe lowo Olorun fun oore nla to se fun oun yii. O sapejuwe moto nla naa gege bii ebun ojoobi oun.
Awa naa ba King Rokan dupe lowo Olorun fun oore nla yii, emi won yoo lo o lagbara Olorun.
No comments:
Post a Comment