IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 10 August 2021

Gongo so lojo ti Yeye Bidemi Olukuewu sayeye oku mama e


Gongo so lojo Aiku, Sannde to koja yii, ojo naa ni gbajugbaja sorosoro ori radio ati telifisan, Yeye Abidemi Olukuewu seye ikeyin fun mama e.

Bamubamu lawon eeyan kun inu gbongan Classic ti ayeye naa ti waye. Gbajugbaja osere fuji nni, Alaaji Sule Also Adekunle Malaika lo forin dara lojo naa. 

Bee ni agbalagba akewi nni, Oloye Sulaiman Aremu Ajobiewe naa dara lojo naa. 

No comments:

Post a Comment

Adbox