IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 13 December 2019

Gbajugba olorin ẹmi, Dọkita Rotimi Onimọlẹ gba ami-ẹye nla latọwọ ẹgbẹ MAAN

Ọjọ nla ti gbajumọ olorin ẹmi ti gbogbo aye fẹran daadaa, Ambandọ Oluwarotimi Okikiọla Onimọle ti gbogbo aye mọ si Ọba Ara ko ni gbagbe bọrọ lanaa, ọjọ kejila, oṣu, kejila, ọdun yii, ọjọ nla yii ni ẹgbẹ awọn to n ta kasẹẹti awọn olorin torukọ wọn n jẹ 'MAAN' fun oṣere nla yii lami-ẹyẹ nla fun ipa nla ati ipa ribiribi to ko fun idagbasoke orin lorile-ede yii.



Leyin ti wọn fun Ọba Ara tawọn ololufẹ tun n pe ni Agbọmabiwọn   fi orin aladun da awọn eeyan lara ya, ti gbogbo oju agbo dun yugbayugba.

No comments:

Post a Comment

Adbox