IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Thursday, 3 October 2019

OPE O:AGBA-OJE OSERE TIATA YORUBA, OGOGO DI ASOJU ILEESE AL-HATYQ TRAVEL AND TOURS LIMITED

Iroyin ayo to te wa lowo bayii ni pe agba-oje osere tiata Yoruba nni, Alaaji Taiwo Hassan ti gbogbo aye mo si Ogogo, ti di asoju ileese to n ba ni seto irinjo lo si oke okun, iyen 'Al-Hatyq Travel and tours limited'. Gege bi a se gbo, ose to koja lohun-un ni Ogogo  to je omo bibi ilu Ilaro, nipinle Ogun towo bowe adehun pelu awon oga ileese Al-Hatyq.

Pelu ohun to sele yii, Ogogo naa ti darapo mo awon gbajugbaja osere bii: Alaaji Wasiu Alabi Pasuma, Alaaji Sefiu Alao Adekunle Baba Oko, Alaaji Giwa Ebunlorin, Alaaja Maryam Akiki atawon irawo osere mi-in ti won je asoju ileese Al-Hatyq Travel and Tours.    




No comments:

Post a Comment

Adbox