IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 23 October 2019

EGBE AWON OLORIN ISMAN EKO BURA FAWON OLOYE TUNTUN

Ojo nla ti igun keji egbe awon olorin Islam, iyen 'ISMAN' tipinle Eko ko ni i gbagbe boro lojo Isegun, Tuesde ana. Ojo naa ni won bura fawon oloye egbe tuntun.

Inu gbongan mosalasi nla 'Wahab Iyanda Folawiyo' to wa ni Surulere layeye ibura naa ti waye. Looya egbe naa lo bura fawon oloye tuntun yii.

Gomina tuntun ti won bura fun Haji Taofeek Agbabiiaka ti won n pe ni Ta-n-mo-la, nigba ti Alaaja Mistura Aderohunmu je akowe eto ayeye egbe yii. Haji Fata Sanni ti won n pe ni Omo Jeeje ni akowe. Gbajugbaja olorin Islam nni, Alaaji AbdulAzeez Salami Ajiroba ti won n pe ni Saoti Arewa lo forin gbe awon oloye tuntun yii jade sori ibi ti won ti fun loye won.










































































Bakan naa ni agba-oje olorin Islam nni, Alaaji Wasiu Kayode As-Sidik to je akowe baba isale egbe yii naa wa nikale. 
Die ninu awon foto ti Ojutole ya nibe ree      

No comments:

Post a Comment

Adbox