Awon eeyan yii ni bii oba nileese Al-Hatyq se awon ati pe gbogbo ibi to ye kawon de gege bi esin se la sile lawon de ati pe gbogbo ise oloore to ye kawon se pata lawon ri se nipase ileese naa.
Awon eayan yii wa a seleri pe ni gbogbo igba tawon ba ti fee lo si hajji ati umrah ileese 'Al-Hatyq' lawon ati gbogbo ebi awon yoo ba lo, nitori pe gbogbo ohun ti won n se nileese naa pelu iberu Olorun ati pe omoluabi eniyan ni oga ileese naa atawon ti won jo n sise papo.
No comments:
Post a Comment