IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 2 July 2019

GBAJUGBAJA SOROSORO, FEYIKEMI OLAYINKA FEE SE IDANILEKOO EDE YORUBA FAWON OMODE


Ninu atejade ti won fi sowo si wa lati ri i pe ileewe 'Lagos Progressive Primary School' to wa ni opopona Mba, ka too de opopona Tafa Balewa ni Adeniran Ogunsanya nidanilekoo naa yoo ti waye, bere lati aago mewaa aaro si aago kan osan.
Idanilekoo odun yii ni yoo je eleekarun-un ti yoo waye
  

No comments:

Post a Comment

Adbox