IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 2 June 2019

LABAKE OROBO, GBAJUMO SOROSORO LO N SOJOOBI

Gbogbo wa pata nileese Ojutole la ki ore wa daadaa, Arabinrin Olabisi Odeyale ti gbogbo aye mo si Labake Orobo ku oriire ojoobi e to waye loni-in.

Adura wa fun omo olojoobi ni pe ko se opo odun ninu owo, ola, alaafia ati emi gigun. Igba odun, iseju aaya ni.

No comments:

Post a Comment

Adbox