Ninu atejade kan ti oga ileese
ohun, Otunba Mutiu Wale Badmus, eni tawon eeyan tun mo si Wale Ticket fi sowo si wa lo ti fidi e mule wi
pe, ise ti n lo lori bi awon Musulumi ti won fe ba ileese ohun lo si ile Mecca
lodun yii yoo se sise ohun lasepe.
O ni, “Ileese nla kan nileese Al-Hatyq Travels and Tours ta a ba n so nipa ki a ko awon eeyan lo si ile mimo
fun ise hajj, awa ko ni i farapamo je enikeni niya, nitori iberu Olorun la wa
fi n se ohun gbogbo ti a ba dawole.
Ise hajj odun 1440 A.H yii, iyen hajj odun
2019, iforukosile ti bere lodo wa, bee lawon eto to maa je ki gbogbo ise
Alalaaji lo niroroun pata la ti n sare e bayii. Se irorun awon alabaara wa lo
je wa logun, ohun lo si se pataki si wa pupo.
Ojo ti a ba so pe a maa gbera naa la maa lo, bee lojo ti a ba so pe
a maa de pada si Nigeria ko ni i ye, eto itoju ati amojuto ilera awon to fe ba wa
rin irin-ajo naa se pataki pupo si wa, bee lawon eeyan yoo si dupe, nitori
ijosin alasepe ni won yoo se pelu ileese Al-Hatyq Travel and Tours Limited to fe ko won lo.
“Awon ti won ti ba wa rin irin-ajo
yii daadaa mo wi pe, ileese to se fokan tan ni wa, bee la kunju osunwon daadaa
ta a ba n so nipa ki a ba eeyan seto irin-ajo si oke okun kaakiri agbaye.”
Awon nomba te e le pe awon alase
ileese Al-Hatyq si ree fun ekunrere alaye: 0803 406 9272
Bakan naa le tun le kan si wa nileese wa to wa ni:935 Lagos/Abeokuta Exp.Rd. Alakuko/Amje Bstop, Alakuko,Lagos, Nigeria.
Lagos, Nigeria
No comments:
Post a Comment