IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 31 May 2019

BI IGBEYAWO KUNLE AFOLAYAN ONITIATA SE DARU REE

O pe daadaa ti oro naa ti n sele labenu laarin won, sugbon won ko fe kawon eeyan gbo, oku oru ni won n fi oro naa se. Gbajumo osere ori itage nni, Kunle Afolayan atiyawo e, Tolu la n so, ohun ti a gbo bayii ni pe aarin okunrin naa ati ololufe e ti daru patatapata.

Nibi ti wahala naa lagbara de, a gbo pe Tolu ti ko kuro nile toun ati oko e gbe, o si ti gba looya ti yoo fi ba Kunle sejo, beeni  Kunle ti so fun adajo pe oun ni ki won ko awon omo to wa laarin awon fun.

Gege bi enikan to mo nipa isele yii se so fun wa, won ni oro owo ati ife ti ko si laarin won mo lo fa wahala yii, nitori pe Tolu to je omo bibi orile-ede Amerika la gbo pe o n gbo bukaata ile, won ni opo igba ni Tolu ti fesun kan oko e pe o n yan ale, ti oro naa si di wahala nla laarin won, yato ti eyi, won ni laipe yii ni Kunle so fun iyawo e pe ko je kawon loo se faaji ni Amerika  pelu awon omo awon, sugbon ti Tolu so pe Dubai ni ko je kawon lo, o ni owo Dubai loun ni, oro yii lo di wahala nla laarin won, ti Tolu fi loo fowo e ra ile, ni ile naa ba tun di wahala.  

Bakan naa la tun gbo pe Tolu naa ti ri okunrin olowo kan ti won jo n se wole-wode bayii, koda won ni omo jayejaye naa sese ra moto olowo nla fun un ni
  

No comments:

Post a Comment

Adbox