Lojokojo, nigbakigba ati nibikibi ti won ba ti n daruko awon obinrin olorin Islam ti won mo tifun-tedo orin, ti won n fi asikiri gbe Olorun ga, bo si je awon olorin Islam to loruko gidi ni won n wi,ohun to daju saka ni pe won ko ni i ri jina ti won yoo fi daruko Alaaja Seidat Bashirat Ogunremi Olomitutu ti gbogbo aye mo si Iya-n-Ghana si i, oodu lobinrin naa ki i saimo foloko.Eyin eeyan wa, eyin naa e wo Iya-n-Ghana, e wo arewa obinrin yii bo se fi ewa re gbe esin Islam ga.

No comments:
Post a Comment