Ninu atejade ti okan ninu awon omo-omo mama yii, Oloye Adeyemi Akinrinade Alayeluwa ilu Houston Texas fi sowo si wa lo ti so pe ojo kejila, osun kin in ni, odun 2019 lasekagba ayeye oku mama yoo waye ni papa-isere ilu Eruwa, iyen Eruwa Stadium.
Ki Olorun tunbo ba wa te mama si afefe ire
Okan ninu awon omo-omo mama, Alayeluwa Houston Texas |
No comments:
Post a Comment