Gbogbo wa pata nileese ojutole la ki eeyan wa daadaa, Arabinrin Rufai Baseerat Omowunmi, okan pataki ninu awon oloye egbe 'Iya-n-Ghana Fans Club' fun ayeye ojoobi e to waye loni-in. A ba a dupe lowo Olorun fun ojo oni, adura wa ni pe ko se opo odun laye ninu ola, owo, ola ati alaafia ara. Igba odun, iseju aaya ni.

No comments:
Post a Comment