IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday 17 December 2018

O MA SEO, SAURA AKERE, OLORIN FUJI TI KU O

Asiko yii ki i se asiko kan gidi fun awon osere fuji ile wa, okan ninu won, Alaaji Surajudeen Saura Alamu Akere, lo jade laye, won si ti sinkuu okunrin naa nilana esin Islam.

Aisan raipe la gbo pe o ko lu osere yii tolojo fi de. Saura ti okiki e kan kaakiri laarin odun 1980 lo ko orin saje kan to gba gbogbo aye. Orin ohun lo ko bayii, 'Bebe Isila eti odo, ta a lo ni bebe isila Olorun lo ni bebe isila'.



Ki Olorun te e safefe ire.   

No comments:

Post a Comment

Adbox