Gbajumo olorin emin nni, Efanjeliisi Dare Melody ti padanu iya-iya e, aaro oni ni mama naa dagbere faye.Ninu oro osere naa lo ti so pe oun padanu okan ninu awon eeyan ti oun feran ju. O ni ipa nla ni mama naa ko nigbesi aye oun koun too di eni nlalawujo.

No comments:
Post a Comment