Ti won ba daruko awon afaadua-jagun ti won n lo alukuraani lati fi tu awon eeyan sile, won yoo daruko okunrin omo bibi ipinle Kwara yii si i, sugbon opo ni ko mo asiiri to wa ninu oruko Oluomo Kutonu ti gbogbo aye n pe e. Ose to koja yii lakoroyin Ojutole sabewo si okunrin naa lofiisi e to wa niluu Ekoo,ojo yii lo so idi ti won se n fun un loruko naa fun wa.
Ninu iforowero ti a se fun un lo ti tu asiiri oruko kan to n je naa fun wa, alaye to se ni pe awon omo Yoruba ti won wa ni Kutonu ni won panupo so oun loruko yii, nitori ipa oun lati ri i pe orile-ede yii lo soke nibe. Bakan naa lo so pe oun dupe lowo Olorun pe oun wa lara awon omo orile-ede yii ti Olorun jogun ile fun ni Kutonu.
Fun itusile lowo gbogbo oogun aye ati idaamu,e pe Oluomo sori nomba yii:0810297759 tabi + 22997831150
No comments:
Post a Comment