Gbogbo wa pata nileese Ojutole la ki eeyan wa daadaa, Iya Obama, olori gbogbo awon obinrin ninu egbe APC l'Amerika ati oga ileese Obankie Castle. Adura wa ni pe ki Mama Obama sopo odun laye ninu owo, ola ati alaafia to peye. Igba odun,iseju aaya ni

No comments:
Post a Comment